Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 18:6 BIBELI MIMỌ (BM)

bí kò bá bá wọn jẹ ẹbọ lórí àwọn òkè, tabi kí ó bọ àwọn oriṣa ilé Israẹli; tí kò bá bá aya aládùúgbò rẹ̀ lòpọ̀, tabi kí ó bá obinrin lòpọ̀ ní àkókò tí ó ń ṣe nǹkan oṣù rẹ̀ lọ́wọ́;

Ka pipe ipin Isikiẹli 18

Wo Isikiẹli 18:6 ni o tọ