Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 18:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí olódodo bá yipada kúrò ninu ìwà òdodo rẹ̀, tí ó bẹ̀rẹ̀ sí dẹ́ṣẹ̀, yóo kú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí ó dá.

Ka pipe ipin Isikiẹli 18

Wo Isikiẹli 18:26 ni o tọ