Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 18:23 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní: “A máa ṣe pé mo ní inú dídùn sí ikú ẹlẹ́ṣẹ̀ ni? Ṣebí ohun tí mo fẹ́ ni pé kí ó yipada kúrò lọ́nà burúkú rẹ̀, kí ó sì yè.

Ka pipe ipin Isikiẹli 18

Wo Isikiẹli 18:23 ni o tọ