Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 18:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó bá ṣẹ̀ ni yóo kú: ọmọ kò ní jìyà ẹ̀ṣẹ̀ baba rẹ̀; baba kò sì ní jìyà ẹ̀ṣẹ̀ ọmọ rẹ̀. Olódodo yóo jèrè òdodo rẹ̀; bẹ́ẹ̀ sì ni eniyan burúkú yóo jèrè ìwà burúkú rẹ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 18

Wo Isikiẹli 18:20 ni o tọ