Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 18:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Baba rẹ̀ yóo kú ní tirẹ̀, nítorí pé ó ń fi ipá gbowó, ó ń ja arakunrin rẹ̀ lólè, ó sì ń ṣe ohun tí kò dára sí àwọn eniyan rẹ̀; nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tirẹ̀ ni yóo ṣe kú.

Ka pipe ipin Isikiẹli 18

Wo Isikiẹli 18:18 ni o tọ