Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 18:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA tún bá mi sọ̀rọ̀, ó bi mí pé:

2. “Kí ni ẹ rí tí ẹ fi ń pa irú òwe yìí nípa ilẹ̀ Israẹli, tí ẹ̀ ń sọ pé,‘Àwọn baba ni wọ́n jẹ èso àjàrà tí ó kan,ni eyín fi kan àwọn ọmọ?’

Ka pipe ipin Isikiẹli 18