Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 17:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Wí fún wọn pé, OLUWA Ọlọrun ní idì ńlá kan wá sí Lẹbanoni, apá rẹ̀ tóbi, ìrù rẹ̀ sì gùn, ó sì ní ìyẹ́ aláràbarà. Ó bá bà lé ṣóńṣó orí igi kedari kan,

Ka pipe ipin Isikiẹli 17

Wo Isikiẹli 17:3 ni o tọ