Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 17:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Idà ni wọn óo fi pa àwọn tí wọ́n bá sá lára àwọn ọmọ ogun rẹ̀, a óo sì fọ́n àwọn tí wọ́n bá kù ká sí gbogbo ayé, ẹ óo wá mọ̀ pé èmi OLUWA ni mo sọ̀rọ̀.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 17

Wo Isikiẹli 17:21 ni o tọ