Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 17:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, OLUWA Ọlọrun ní, “Mo fi ara mi búra, n óo gbẹ̀san ìbúra mi tí kò náání lára rẹ̀, ati majẹmu mi tí ó dà.

Ka pipe ipin Isikiẹli 17

Wo Isikiẹli 17:19 ni o tọ