Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 17:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n bá tún un gbìn ǹjẹ́ yóo yè? Ṣé kò ní gbẹ patapata nígbà tí afẹ́fẹ́ ìlà oòrùn bá fẹ́ lù ú? Yóo gbẹ níbi tí wọ́n gbìn ín sí.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 17

Wo Isikiẹli 17:10 ni o tọ