Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 16:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wá wọ̀ ọ́ ní aṣọ tí wọ́n ṣe ọnà sí lára, mo wọ̀ ọ́ ní bàtà aláwọ. Mo wọ̀ ọ́ ní aṣọ funfun, mo sì dá ẹ̀wù siliki fún ọ.

Ka pipe ipin Isikiẹli 16

Wo Isikiẹli 16:10 ni o tọ