Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 14:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn yóo jẹ́ ìtùnú fún ọ nígbà tí o bá rí ìwà ati ìṣe wọn, O óo sì mọ̀ pé bí kò bá nídìí, n kò ní ṣe gbogbo ohun tí mo ṣe sí wọn. Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 14

Wo Isikiẹli 14:23 ni o tọ