Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 14:16 BIBELI MIMỌ (BM)

bí Noa, ati Daniẹli ati Jobu bá tilẹ̀ wà níbẹ̀, bí èmi OLUWA Ọlọrun fi ara mi búra pé, wọn kò ní lè gba ọmọkunrin tabi ọmọbinrin wọn là. Ara wọn nìkan ni wọn yóo lè gbàlà, ilẹ̀ náà yóo sì di ahoro.

Ka pipe ipin Isikiẹli 14

Wo Isikiẹli 14:16 ni o tọ