Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 13:22 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí pé ẹ̀ ń fi àrékérekè ba àwọn olódodo lọ́kàn jẹ́, nígbà tí n kò fẹ́ bà wọ́n lọ́kàn jẹ́; ẹ sì ń ṣe onígbọ̀wọ́ àwọn eniyan burúkú kí wọn má baà yipada lọ́nà ibi wọn, kí wọn sì rí ìgbàlà.

Ka pipe ipin Isikiẹli 13

Wo Isikiẹli 13:22 ni o tọ