Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 13:16 BIBELI MIMỌ (BM)

àwọn wolii Israẹli tí wọn ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa Jerusalẹmu tí wọn ń ríran alaafia nípa rẹ̀, nígbà tí kò sí alaafia. Bẹ́ẹ̀ ni èmi OLUWA Ọlọrun wí.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 13

Wo Isikiẹli 13:16 ni o tọ