Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 13:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí odi náà bá wó, ǹjẹ́ àwọn eniyan kò ní bi yín pé, ‘Ọ̀dà funfun tí ẹ fi ń kun ara rẹ̀ ńkọ́?’ ”

Ka pipe ipin Isikiẹli 13

Wo Isikiẹli 13:12 ni o tọ