Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 12:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, wí fún wọn pé: mo ní n kò ní fi ọ̀rọ̀ mi falẹ̀ mọ́, ṣugbọn ohun tí mo bá sọ yóo ṣẹ. Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo wí bẹ́ẹ̀.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 12

Wo Isikiẹli 12:28 ni o tọ