Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 12:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó jẹ́ olórí láàrin wọn yóo gbé ẹrù rẹ̀ lé èjìká ní alẹ́, yóo sì jáde kúrò nílùú. Yóo dá odi ìlú lu, yóo gba ibẹ̀ jáde. Yóo fi nǹkan bojú kí ó má ba à rí ilẹ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 12

Wo Isikiẹli 12:12 ni o tọ