Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 11:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí mo tí ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ lọ́wọ́ ni Pelataya, ọmọ Bẹnaya, bá kú. Mo bá dojúbolẹ̀, mo kígbe sókè, mo ní, “Áà! OLUWA Ọlọrun, ṣé o fẹ́ pa àwọn ọmọ Israẹli yòókù tán ni?”

Ka pipe ipin Isikiẹli 11

Wo Isikiẹli 11:13 ni o tọ