Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 10:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀kọ̀ọ̀kan ninu wọn ní iwájú mẹrin mẹrin. Iwájú kinni jẹ́ iwájú Kerubu, ekeji jẹ́ iwájú eniyan, ẹkẹta jẹ́ iwájú kinniun, ẹkẹrin sì jẹ́ iwájú ẹyẹ idì.

Ka pipe ipin Isikiẹli 10

Wo Isikiẹli 10:14 ni o tọ