Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 1:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wò ó láti ibi tí ó dàbí ìbàdí rẹ̀ lọ sókè, ó rí bíi bàbà dídán, ó dàbí iná yíká. Mo wò ó láti ibi ìbàdí lọ sí ìsàlẹ̀, ó dàbí iná. Ìmọ́lẹ̀ sì wà ní gbogbo àyíká rẹ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 1

Wo Isikiẹli 1:27 ni o tọ