Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nǹkankan wà láàrin àwọn ẹ̀dá alààyè náà tí ó dàbí ẹ̀yinná tí ń jó. Ó ń lọ sókè sódò láàrin wọn bí ahọ́n iná. Iná náà mọ́lẹ̀, ó sì ń kọ mànàmànà.

Ka pipe ipin Isikiẹli 1

Wo Isikiẹli 1:13 ni o tọ