Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hosia 6:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn óo wí pé, “Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á pada sọ́dọ̀ OLUWA; nítorí bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti fà wá ya, sibẹ yóo wò wá sàn; ó ti pa wá lára lóòótọ́, ṣugbọn yóo di ọgbẹ́ wa.

Ka pipe ipin Hosia 6

Wo Hosia 6:1 ni o tọ