Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hosia 5:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ gbọ́, ẹ̀yin alufaa! Ẹ tẹ́tí sílẹ̀, ẹ̀yin ọmọ Israẹli ati ẹ̀yin ìdílé ọba! Ẹ̀yin ni ìdájọ́ náà dé bá; nítorí ẹ dàbí tàkúté ní Misipa, ati bí àwọ̀n tí a ta sílẹ̀ lórí òkè Tabori.

Ka pipe ipin Hosia 5

Wo Hosia 5:1 ni o tọ