Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hosia 4:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan mi ń ṣègbé nítorí àìsí ìmọ̀; nítorí pé ẹ̀yin alufaa ti kọ ìmọ̀ mi sílẹ̀, èmi náà yóo kọ̀ yín ní alufaa mi. Nítorí pé ẹ ti gbàgbé òfin Ọlọrun yín, èmi náà yóo gbàgbé àwọn ọmọ yín.

Ka pipe ipin Hosia 4

Wo Hosia 4:6 ni o tọ