Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hosia 3:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Israẹli yóo pada tọ OLUWA Ọlọrun wọn, ati Dafidi, ọba wọn lọ. Wọn yóo fi ìbẹ̀rù wá sọ́dọ̀ OLUWA, wọn yóo sì gba oore rẹ̀ ní ọjọ́ ìkẹyìn.

Ka pipe ipin Hosia 3

Wo Hosia 3:5 ni o tọ