Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hosia 14:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Asiria kò lè gbà wá là, bẹ́ẹ̀ ni a kò ní gun ẹṣin; a kò sì ní pe oriṣa, tíí ṣe iṣẹ́ ọwọ́ wa, ní Ọlọrun wa mọ́. OLUWA, ìwọ ni ò ń ṣàánú fún ọmọ tí kò lẹ́nìkan.”

Ka pipe ipin Hosia 14

Wo Hosia 14:3 ni o tọ