Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hosia 13:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, wọn óo dàbí ìkùukùu òwúrọ̀, ati bí ìrì tíí máa ń yára gbẹ, wọ́n óo dàbí ìyàngbò tí afẹ́fẹ́ ń fẹ́ kúrò ní ibi ìpakà, ati bí èéfín tí ń jáde láti ojú fèrèsé.

Ka pipe ipin Hosia 13

Wo Hosia 13:3 ni o tọ