Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hosia 10:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbin òdodo fún ara yín, kí ẹ sì ká èso ìfẹ́ tí kì í yẹ̀; ẹ lọ dá oko sí ilẹ̀ tí ẹ ti kọ̀ sílẹ̀, nítorí ó tó àkókò láti wá OLUWA, kí ó lè wá rọ ìgbàlà le yín lórí bí òjò.

Ka pipe ipin Hosia 10

Wo Hosia 10:12 ni o tọ