Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hosia 10:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli dàbí àjàrà dáradára tí ń so èso pupọ. Bí èso rẹ̀ tí ń pọ̀ sí i, bẹ́ẹ̀ ni pẹpẹ oriṣa wọn ń pọ̀ sí i. Bí àwọn ìlú wọn tí ń dára sí i ni àwọn ọ̀wọ̀n oriṣa wọn náà ń dára sí i.

Ka pipe ipin Hosia 10

Wo Hosia 10:1 ni o tọ