Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hagai 2:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ògo tí ilé yìí yóo ní tó bá yá, yóo ju ti àtijọ́ lọ. N óo fún àwọn eniyan mi ní alaafia ati ibukun ninu rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun wí.”

Ka pipe ipin Hagai 2

Wo Hagai 2:9 ni o tọ