Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hagai 2:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn, mú ọkàn le, ìwọ Serubabeli, má sì fòyà, ìwọ Joṣua, ọmọ Jehosadaki, olórí alufaa; ẹ ṣe ara gírí kí ẹ sì ṣe iṣẹ́ náà ẹ̀yin eniyan; nítorí mo wà pẹlu yín. Bẹ́ẹ̀ ni èmi OLUWA wí.

Ka pipe ipin Hagai 2

Wo Hagai 2:4 ni o tọ