Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hagai 2:22 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo lé àwọn ìjọba kúrò ní ipò wọn; n óo sì ṣẹ́ àwọn ìjọba orílẹ̀-èdè lápá. N óo ta kẹ̀kẹ́ ogun ati àwọn tí wọn ń gùn wọ́n lókìtì. Ẹṣin ati àwọn tí wọn ń gùn wọ́n yóo ṣubú, wọn óo sì fi idà pa ara wọn.

Ka pipe ipin Hagai 2

Wo Hagai 2:22 ni o tọ