Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hagai 2:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Tún lọ sọ́dọ̀ Serubabeli ọmọ Ṣealitieli, gomina ilẹ̀ Juda, ati Joṣua ọmọ Jehosadaki, olórí alufaa ati gbogbo àwọn eniyan tí wọ́n ṣẹ́kù, kí o bèèrè pé,

Ka pipe ipin Hagai 2

Wo Hagai 2:2 ni o tọ