Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Habakuku 3:2 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, mo ti gbọ́ òkìkí rẹ,mo sì bẹ̀rù iṣẹ́ ọwọ́ rẹ.Gbogbo bí ò ó tíí ṣe tí à ń gbọ́;tún wá ṣe bẹ́ẹ̀ nígbà tiwa;sì ranti àánú ní àkókò ibinu rẹ.

Ka pipe ipin Habakuku 3

Wo Habakuku 3:2 ni o tọ