Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Habakuku 3:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun, OLUWA, ni agbára mi;Ó mú kí ẹsẹ̀ mi yá nílẹ̀ bíi ti àgbọ̀nrín,ó mú mi rìn lórí àwọn òkè gíga.(Sí ọ̀gá akọrin; pẹlu àwọn ohun èlò orin olókùn.)

Ka pipe ipin Habakuku 3

Wo Habakuku 3:19 ni o tọ