Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Habakuku 3:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Oòrùn ati òṣùpá dúró ní ipò wọn,nígbà tí ọfà rẹ ń já lọ ṣòòrò,tí àwọn ọ̀kọ̀ rẹ náà ń kọ mànà,bí wọ́n ti ń fò lọ.

Ka pipe ipin Habakuku 3

Wo Habakuku 3:11 ni o tọ