Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Habakuku 2:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ǹjẹ́ gbogbo àwọn eniyan wọnyi kò ní máa kẹ́gàn rẹ̀, kí wọ́n sì máa fi ṣe ẹlẹ́yà pé, “Ègbé ni fún ẹni tí ń kó ohun tí kì í ṣe tirẹ̀ jọ. Ìgbà wo ni yóo ṣe èyí dà, tí yóo máa gba ìdógò lọ́wọ́ àwọn onígbèsè rẹ̀ kiri?”

Ka pipe ipin Habakuku 2

Wo Habakuku 2:6 ni o tọ