Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Habakuku 1:2 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, yóo ti pẹ́ tó, tí n óo máa ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́; tí o kò sì ní dá mi lóhùn? Tí n óo máa ké pé, “Wo ìwà ipá!” tí o kò sì ní gba olúwarẹ̀ sílẹ̀?

Ka pipe ipin Habakuku 1

Wo Habakuku 1:2 ni o tọ