Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Habakuku 1:12 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, ṣebí láti ayérayé ni o ti wà? Ọlọrun mi, Ẹni Mímọ́ mi, a kò ní kú. OLUWA, ìwọ ni o yan àwọn ará Babiloni gẹ́gẹ́ bí onídàájọ́. Ìwọ Àpáta, ni o gbé wọn kalẹ̀ bíi pàṣán, láti jẹ wá níyà.

Ka pipe ipin Habakuku 1

Wo Habakuku 1:12 ni o tọ