Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsita 9:27 BIBELI MIMỌ (BM)

ni àwọn Juu fi sọ ọ́ di òfin fún ara wọn, ati fún arọmọdọmọ wọn, ati fún àwọn tí wọ́n bá di Juu, pé ní àkókò rẹ̀, ní ọdọọdún, ọjọ́ mejeeji yìí gbọdọ̀ jẹ́ ọjọ́ àsè, gẹ́gẹ́ bí àṣẹ Modekai,

Ka pipe ipin Ẹsita 9

Wo Ẹsita 9:27 ni o tọ