Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsita 9:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Modekai kọ gbogbo nǹkan wọnyi sílẹ̀, Ó sì fi ranṣẹ sí àwọn Juu tí wọ́n wà ní gbogbo ilẹ̀ ìjọba Ahasu-erusi ọba, ati àwọn tí wọ́n wà nítòsí ati àwọn tí wọ́n wà ní òkèèrè,

Ka pipe ipin Ẹsita 9

Wo Ẹsita 9:20 ni o tọ