Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsita 8:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Kọ ohunkohun tí ó bá wù ọ́ nípa àwọn Juu ní orúkọ ọba, kí o sì fi òrùka ọba tẹ̀ ẹ́ bí èdìdì. Nítorí pé òfin tí a bá kọ ní orúkọ ọba, tí ó sì ní èdìdì ọba, ẹnikẹ́ni kò lè yí i pada mọ́.”

Ka pipe ipin Ẹsita 8

Wo Ẹsita 8:8 ni o tọ