Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsita 8:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní gbogbo agbègbè, ati ní àwọn ìlú tí ìkéde yìí dé, ìdùnnú ati ayọ̀ kún inú àwọn Juu, wọ́n se àsè pẹlu ayẹyẹ, wọ́n sì gba ìsinmi. Àwọn ẹ̀yà mìíràn sọ ara wọn di Juu, nítorí pé ẹ̀rù àwọn Juu ń bà wọ́n.

Ka pipe ipin Ẹsita 8

Wo Ẹsita 8:17 ni o tọ