Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsita 8:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ náà gan-an ni ọba Ahasu-erusi fún Ẹsita Ayaba ní ilé Hamani, ọ̀tá àwọn Juu. Ẹsita wá sọ fún ọba pé eniyan òun ni Modekai. Láti ìgbà náà ni ọba sì ti mú Modekai wá siwaju rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹsita 8

Wo Ẹsita 8:1 ni o tọ