Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsita 7:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba dìde kúrò ní ibi àsè náà pẹlu ibinu, ó jáde lọ sinu àgbàlá ààfin. Nígbà tí Hamani rí i pé ọba ti pinnu ibi fún òun, ó dúró lẹ́yìn láti bẹ Ẹsita Ayaba fún ẹ̀mí rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹsita 7

Wo Ẹsita 7:7 ni o tọ