Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsita 6:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Hamani tí ń wọlé ni ọba bi í pé, “Kí ló yẹ kí á ṣe fún ẹni tí inú ọba dùn sí?”Hamani rò ó ninu ara rẹ̀ pé, ta ni ọba ìbá tún dá lọ́lá bíkòṣe òun.

Ka pipe ipin Ẹsita 6

Wo Ẹsita 6:6 ni o tọ