Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsita 4:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Modekai gbọ́ gbogbo ohun tí ó ṣẹlẹ̀, ó fa aṣọ rẹ̀ ya. Ó fi àkísà ati eérú bo ara rẹ̀. Ó kígbe lọ sí ààrin ìlú, ó ń pohùnréré ẹkún.

Ka pipe ipin Ẹsita 4

Wo Ẹsita 4:1 ni o tọ