Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsita 3:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Hamani lọ bá Ahasu-erusi ọba, ó sọ fún un pé, “Àwọn eniyan kan wà tí wọ́n fọ́n káàkiri ààrin àwọn eniyan ati ní gbogbo agbègbè ìjọba rẹ; òfin wọn kò bá ti gbogbo eniyan mu, wọn kò sì pa àṣẹ ọba mọ́. Kò dára kí o gbà wọ́n láàyè ninu ìjọba rẹ.

Ka pipe ipin Ẹsita 3

Wo Ẹsita 3:8 ni o tọ