Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsita 3:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn olóyè ní ẹnu ọ̀nà ààfin ọba a sì máa foríbalẹ̀ láti bu ọlá fún Hamani, gẹ́gẹ́ bí àṣẹ ọba, ṣugbọn Modekai kò jẹ́ foríbalẹ̀ kí ó bu ọlá fún Hamani.

Ka pipe ipin Ẹsita 3

Wo Ẹsita 3:2 ni o tọ